Orílè'dè Yorùbá

Orílè'dè Yorùbá Ilẹ̀ Káàárọ̀-Oòjíire

28/05/2023

Ẹjọ se ose gbọ ṣétí wípé Ọmọ Yorùbá ní Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kí ìyà tún máa jẹ Ìran Yorùbá?

31/12/2022
13/12/2022

Akoko Agidi
Awori Agidi
Ekiti Agidi
Egba Agidi
Ijebu Agidi
Ijesha Agidi
Ife Agidi
Ikale Agidi
Ibadan Agidi
Ibarapa Agidi
Ibolo Agidi
Ondo Agidi
Oyo Agidi
Oke-ogun Agidi
Ejo eya Yoruba wo ni ko ni agidi?
Ki ni oun to Dara ti afi Agidi wa see ri?
Agidi ati agbara wa eje ka fi ba awon ota ilewa ja. Faramon Idasile orilede yoruba Loni. Orilede emi ati iwo ni.

19/11/2022

KO KAN WA OOO,
SUGBON EFI EYI KOGBON.
EJO NINU ISEJOBA SANI ABACHA ATI MUHAMODU BUHARI. EWO LO DARA JU?

18/11/2022

JE KI INU RE KO MA DUN NIGBAKUGBA TI O BA TI N GBO OUN KOUN TO JE MO TI
Orílè'dè Yorùbá.
ORILEDE GBOGBO WA NI.

17/11/2022

ISOKAN YORUBA
FUN YORUBA, LARIN YORUBA,
NINU ORILEDE YORUBA.

EJOWO EBA WA FI OJU SUNUKUN WO, SE OUN FE AFIKUN TABI AYOKURO?
09/11/2022

EJOWO EBA WA FI OJU SUNUKUN WO, SE OUN FE AFIKUN TABI AYOKURO?

07/11/2022

KOSI ENIYAN TABI ALAGBARA KANKAN TO LE JI NIJERIYA TO TI KU PADA. OLORUN TI FUN WA NI 'ODUDUWA'
TIO WA LATI DAA IKOLO WA PADA.

05/11/2022

LOJU NA ATI JE KI AWON AJO AGBAYE TO N JA FUN ETO OMO ENIYAN O MON PE LOOTO NI OPOLOPO OMO YORUBA N BERE FUN OMINIRA NI ONA TI O BA OFIN MU.
E TELEWA LORI AWON IKANNI WA MEJEJI TOWA NINU AWORAN YI:

-AWON NI AJIJANGBARA AKOKO TI OJE KAMON PE ORILEDE KAN N BO TI YIO MA JE Orílè'dè Yorùbá.-AWON NI WON KO ORIN Orílè'dè Y...
31/10/2022

-AWON NI AJIJANGBARA AKOKO TI OJE KAMON PE ORILEDE KAN N BO TI YIO MA JE Orílè'dè Yorùbá.
-AWON NI WON KO ORIN Orílè'dè Yorùbá.
KINI ORUKO WON?

FUN AWON TI KO MON PE OMO IYA NIWA ATI IBI TI ATISE WA.
29/10/2022

FUN AWON TI KO MON PE OMO IYA NIWA ATI IBI TI ATISE WA.

Address

London

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Orílè'dè Yorùbá posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category